Ní ìsopọ̀ pẹ̀lú àwọn ènìyàn, ibi yòówù, àti àwọn àṣà láìsí ìṣòro nípa èdè
Ṣètúmọ̀ èdè pẹ̀lú kámẹ́rà rẹ
Ṣá ti kọjúu kámẹ́rà rẹ síi, kí o sì ṣètúmọ̀ ohun tí o rí ní kíá
Kò sí Íntánẹ́ẹ̀tì bí? Kò sí ìṣòro.
Gba èdè kan wálẹ̀ lát'ayélujára kí o lè ṣètúmọ̀ láìsí ìsopọ̀ íntánẹ́ẹ̀tì
Bánisọ̀rọ̀
Bá ẹnìkan tí ń sọ èdè mìíràn sọ̀rọ̀
Ṣètúmọ̀ ọ̀rọ̀-sísọ lẹ́ẹ̀kan náà
Tan Ṣàkọsílẹ̀ láti lóye ohun tí a ń sọ
Ṣètúmọ̀ láti inú áàpù yòówù
Èyíówù áàpù tí o lè máa lò, ṣá ti ṣe ẹ̀dà àyọkà, kí o sì fọwọ́bàá láti ṣètúmọ̀
Tẹ̀ẹ́síwé, sọ ọ́, tàbi kí o fọwọ́ kọ ọ́
Lo ìtẹ̀wọlé ohùn tàbí kí o fọwọ́kọ àwọn ẹyọ-ọ̀rọ̀ àti àwọn ọ̀rọ̀ tí àtẹbọ́tìnnì rẹ kò ní àtìlẹ́yìn fún
Ti fipamọ́
Ìṣètúmọ̀ Àkọṣílẹ̀
Ìṣètúmọ̀ èdè Wẹ́ẹ̀bù
Fi àwọn ìṣètúmọ̀ rẹ pamọ́
Ní kíá ráàyèsí àwọn ọ̀rọ̀ àti gbólóhùn láti orí ẹ̀rọ yòówù nípa fífi wọ́n pamọ̀
Kínni ó wà nínú àkọsílẹ̀ yẹn?
Kó àwọn fáìlì rẹ sórí ayélujára láti túmọ̀ wọn lọ́nà àrà ní ibi kan láì pàdánù ètò-ìrísí wọn
Ṣètúmọ̀ àwọn ojúlé wẹ́ẹ̀bù
Ǹjẹ́ o nílò láti ṣètúmọ̀ èdè odidi ojú-ewé wẹ́ẹ̀bù kan bí? Ṣáà tẹ URL kan wọlé láti ṣètúmọ̀ èdè odidi ojú-ewé wẹ́ẹ̀bù kan.
Dán Google Ṣètúmọ̀ wò
Bẹ̀rẹ̀ sí lo Google Ṣètúmọ̀ nínú aṣàwákiri rẹ. Tàbí kí o fi ẹ̀rọ yàwòrán kóòdù QR nísàlẹ̀ láti gba áàpù náà sílẹ̀ fún lílò lórí ẹ̀rọ alágbèéká rẹ.
Gba áàpù náà sílẹ̀ láti ṣàwákiri ayé, kí o sì bá àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀ ní oríṣiríṣi èdè.